ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • lfb ojú ìwé 72-73
  • Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 6

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 6
  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Láti Ìgbà Ìdáǹdè Kúrò ní Íjíbítì sí Àkókò Ọba Àkọ́kọ́ ní Ísírẹ́lì
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Wọ Ilẹ̀ Kénáánì
    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
  • Tá A Bá Jẹ́ Olóòótọ́, A Máa Rí Ojúure Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • Jẹ́fútà Mú Ẹ̀jẹ́ Tó Jẹ́ Fún Jèhófà Ṣẹ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
lfb ojú ìwé 72-73
Sámúsìn gbé géètì ìlú Gásà

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú fún Apá 6

Nígbà táwọn ọmọ Ísírẹ́lì wọ Ilẹ̀ Ìlérí, àgọ́ ìjọsìn ni wọ́n ti máa ń jọ́sìn Jèhófà. Àwọn àlùfáà máa ń kọ́ àwọn èèyàn ní Òfin Ọlọ́run, àwọn onídàájọ́ sì máa ń darí wọn. Apá yìí máa jẹ́ ká rí i pé ohun tí ẹnì kan bá ṣe lè ṣàkóbá fáwọn míì tàbí kó ṣe wọ́n láǹfààní. Gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lẹ́nì kọ̀ọ̀kan ló gbọ́dọ̀ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, kí wọ́n sì tún nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì wọn. Kọ́ ọmọ rẹ nípa Dèbórà, Náómì, Jóṣúà, Hánà, ọmọbìnrin Jẹ́fútà àti Sámúẹ́lì. Jẹ́ kó rí i pé àwọn ìpinnu tí wọ́n ṣe nípa lórí àwọn míì. Tẹnu mọ́ ọn pé àwọn tí kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì pàápàá irú bíi Ráhábù, Rúùtù, Jáẹ́lì àtàwọn ará Gíbéónì pinnu láti wà pẹ̀lú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì torí wọ́n rí i pé Ọlọ́run wà pẹ̀lú wọn.

Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ

  • Jèhófà lo àwọn onídàájọ́ láti gba àwọn èèyàn ẹ̀ sílẹ̀ lọ́nà ìyanu

  • Gbogbo àwọn olóòótọ́ yálà wọ́n jẹ́ ọmọdé tàbí àgbàlagbà ni Jèhófà bù kún torí pé wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé e

  • Gbogbo èèyàn ni Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ láìka ìlú tí wọ́n ti wá, tí wọ́n bá fi hàn pé àwọn nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, tí wọ́n sì ń ṣe rere

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́