ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 69
  • Máa Wàásù Ìjọba Náà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Wàásù Ìjọba Náà
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ Tẹ̀ Síwájú, Ẹ̀yin Òjíṣẹ́ Ìjọba Ọlọ́run!
    Kọrin sí Jèhófà
  • Ẹ Tẹ̀ Síwájú Ẹ̀yin Ẹlẹ́rìí!
    Kọrin sí Jèhófà
  • Ẹ Tẹ̀ Síwájú, Ẹ̀yin Ẹlẹ́rìí
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • À Ń Jẹ́ Kí Orúkọ Wa Máa Rò Wá
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 69

ORIN 69

Máa Wàásù Ìjọba Náà

Bíi Ti Orí Ìwé

(2 Tímótì 4:5)

  1. 1. Ẹ tẹ̀ síwájú, ẹ máa wàásù.

    Ẹ kéde orúkọ Jáà.

    Ẹ wá àwọn onírẹ̀lẹ̀ lọ

    Torí ‘fẹ́ tẹ́ ẹ ní sí wọn.

    Àǹfààní aláìlẹ́gbẹ́ ló jẹ́

    Láti bá Ọlọ́run ṣiṣẹ́.

    Torí náà, ká máa fayọ̀ wàásù;

    Ká kéde òótọ́ fáráyé.

    (ÈGBÈ)

    Tẹ̀ síwájú, fìgboyà wàásù

    ‘Jọba náà fáráyé.

    Tẹ̀ síwájú, kó o jẹ́ adúróṣinṣin

    sí Jèhófà.

  2. 2. Àwọn ẹni àmì òróró

    Àti àgùntàn mìíràn;

    Gbogbo wa lọ́kùnrin, lóbìnrin

    Ni ká máa tẹ̀ síwájú.

    Ó yẹ kí gbogbo ayé gbọ́ pé

    Ìjọba Ọlọ́run dé tán.

    Bá a ṣe ń wàásù, ẹ̀rù kìí bà wá.

    Jèhófà ló wà lẹ́yìn wa.

    (ÈGBÈ)

    Tẹ̀ síwájú, fìgboyà wàásù

    ‘Jọba náà fáráyé.

    Tẹ̀ síwájú, kó o jẹ́ adúróṣinṣin

    sí Jèhófà.

(Tún wo Sm. 23:4; Ìṣe 4:​29, 31; 1 Pét. 2:21.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́