ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 116
  • Agbára Inúure

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Agbára Inúure
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Agbára Inú Rere
    Kọrin sí Jèhófà
  • Inú Rere​—Ànímọ́ Kan Tó Yẹ Kó Hàn Nínú Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Wa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Ó Yẹ Kí Èèyàn Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Inú Rere
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Mú Inu Jehofa Dùn Nipa Fifi Inurere Hàn
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 116

ORIN 116

Agbára Inúure

Bíi Ti Orí Ìwé

(Éfésù 4:32)

  1. 1. Tọkàntọkàn là ń yìn ọ́, Jèhófà

    Torí pé Ọ̀rọ̀ rẹ

    Jẹ́ ká mọ bágbára rẹ ṣe pọ̀ tó,

    Síbẹ̀ ò ń fìfẹ́ hàn sí wa.

  2. 2. Jésù ń pe àwọn tẹ́rù wọn wúwo

    Kí wọ́n wá sọ́dọ̀ rẹ̀.

    Onínúure ni, onírẹ̀lẹ̀ ni;

    Ó máa mú ìtura bá wọn.

  3. 3. Jèhófà àti Jésù Ọmọ rẹ̀

    Ti fàpẹẹrẹ lélẹ̀.

    Tá a bá jẹ́ onínúure bíi tiwọn,

    Yóò sọ wá di alágbára!

(Tún wo Míkà 6:8; Mát. 11:​28-30; Kól. 3:12; 1 Pét. 2:3.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́