ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 11A
Díẹ̀ Lára Àwọn Olùṣọ́ Tó Jẹ́ Àpẹẹrẹ Rere
Bíi Ti Orí Ìwé
Àwọn olùṣọ́ yìí kojú àtakò, wọ́n jẹ́ adúróṣinṣin, wọ́n sì kéde ìhìn rere àti ìkìlọ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run.
ÍSÍRẸ́LÌ ÀTIJỌ́
Àìsáyà 778 sí n. 732 Ṣ.S.K.
Jeremáyà 647 sí 580 Ṣ.S.K.
Ìsíkíẹ́lì 613 sí n. 591 Ṣ.S.K.
ỌGỌ́RÙN-ÚN ỌDÚN KÌÍNÍ
Jòhánù Arinibọmi 29 sí 32 S.K.
Jésù 29 sí 33 S.K.
Pọ́ọ̀lù n. 34 sí n. 65 S.K.
ÒDE ÒNÍ
C. T. Russell àti Àwọn Alábàákẹ́gbẹ́ Rẹ̀ n. 1879 sí 1919
Ẹrú Olóòótọ́ 1919 Títí Dòní