Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Mú Òfin Kristi Ṣẹ!
ÒWÚRỌ̀
9:40 [11:30]a Ohùn Orin
9:50 [11:40] Orin 17 àti Àdúrà
10:00 [11:50] Kí Ni Òfin Kristi?
10:15 [12:05] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ Nígbà Tá A Bá Dá Wà
10:30 [12:20] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù
10:55 [12:45] Orin 70 àti Ìfilọ̀
11:05 [12:55] Kí Nìdí Tí Òfin Kristi Fi Ju Òfin Mósè Lọ?
11:35 [1:25] Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:05 [1:55] Orin 51
Ọ̀SÁN
1:20 [2:35] Ohùn Orin
1:30 [2:45] Orin 76
1:35 [2:50] Ìrírí
1:45 [3:00] Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:15 [3:30] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ Nínú Ìdílé
2:30 [3:45] Bá A Ṣe Lè Mú Òfin Kristi Ṣẹ ní Iléèwé
2:45 [4:00] Orin 35 àti Ìfilọ̀
2:55 [4:10] Ẹ Nífẹ̀ẹ́ Ara Yín Bí Jésù Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Yín
3:55 [5:10] Orin 13 àti Àdúrà
a Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé ní Sátidé tó bá jẹ́ ọjọ́ “Gbálùúmọ́”