Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Ṣe Ohun Tó Dára!
ÒWÚRỌ̀
9:30 [11:30]a Ohùn Orin
9:40 [11:40] Orin 77 àti Àdúrà
9:50 [11:50] Kí Nìdí Tó Fi Ṣòro Láti Ṣe Ohun Tó Dára?
10:05 [12:05] Àpínsọ Àsọyé: Má Ṣe Fúnrúgbìn Pẹ̀lú Níní Ẹran Ara Lọ́kàn
Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò
Yan Eré Ìnàjú Tó Bójú Mu
Kọjú Ìjà sí Ẹ̀mí Ìlara
Máa Lépa Ọjọ́ Ọ̀la Tó Fini Lọ́kàn Balẹ̀
11:05 [1:05] Orin 45 àti Ìfilọ̀
11:15 [1:15] Máa Ṣe Ohun Rere sí Gbogbo Èèyàn
11:30 [1:30] Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:00 [2:00] Orin 63
Ọ̀SÁN
1:10 [2:40] Ohùn Orin
1:20 [2:50] Orin 127 àti Àdúrà
1:30 [3:00] Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Báwo La Ṣe Lè Yẹra fún Fífi Ọlọ́run Ṣe Ẹlẹ́yà?
2:00 [3:30] Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:30 [4:00] Orin 59 àti Ìfilọ̀
2:40 [4:10] Àpínsọ Àsọyé: Máa Fúnrúgbìn Nípa Ti Ẹ̀mí
Jẹ́ Kó Mọ́ Ẹ Lára Láti Máa Kẹ́kọ̀ọ́
Fi Àwọn Ìlànà Bíbélì Darí Ìgbésí Ayé Rẹ
“Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Sinmi”
3:40 [5:10] Ohun Tá A Máa Ká Tí A Kò Bá Ṣàárẹ̀
4:15 [5:45] Orin 126 àti Àdúrà
a Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé ní Sátidé tó bá jẹ́ ọjọ́ “Gbálùúmọ́”