“Ẹ Ní Ìgbàgbọ́”!
ÒWÚRỌ̀
9:30 Ohùn Orin
9:40 Orin 118 àti Àdúrà
9:50 Báwo La Ṣe Lè “Ní Ìgbàgbọ́,” Kí sì Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ní In?
10:05 Àpínsọ Àsọyé: Máa Fara Wé Àwọn Tó Nígbàgbọ́
• Ísákì àti Rèbékà
• Ẹ́sítà
• Tímótì
11:05 Orin 60 àti Ìfilọ̀
11:15 ‘A Ní Ìgbàgbọ́, Torí Náà A Sọ̀rọ̀’
11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:00 Orin 52
Ọ̀SÁN
1:10 Ohùn Orin
1:20 Orin 9 àti Àdúrà
1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run “Tí Kò Lè Parọ́”
2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:30 Orin 54 àti Ìfilọ̀
2:40 Àpínsọ Àsọyé: Máa “Rìn Nípa Ìgbàgbọ́” Lójoojúmọ́
• “Má Ṣàníyàn Láé”
• ‘Máa Lo Àkókò Rẹ Lọ́nà Tó Dára Jù Lọ’
• Má Ṣe Jẹ́ “Apá Kan Ayé”
3:40 “Jèhófà Mọ Àwọn Tó Jẹ́ Tirẹ̀”
4:15 Orin 7 àti Àdúrà