Àpéjọ Àyíká Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ 2017
Ẹṣin Ọ̀rọ̀: Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Rẹ Nínú Jèhófà Máa Lágbára Sí I!—Héb. 11:6
Òwúrọ̀
9:30 [11:30]a Ohùn Orin
9:40 [11:40] Orin 12 àti Àdúrà
9:50 [11:50] Lábẹ́ Ipòkípò, “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run”
10:05 [12:05] Àpínsọ Àsọyé: Àwọn Àfiwé Ọ̀rọ̀ Tó Ń Mú Kí Ìgbàgbọ́ Ẹni Nínú Jèhófà Lágbára
Apata
Baba
Àpáta
Olùṣọ́ Àgùntàn
11:05 [1:05] Orin 22 àti Ìfilọ̀
11:15 [1:15] “Ràn Mí Lọ́wọ́ Níbi Tí Mo Ti Nílò Ìgbàgbọ́!”
11:30 [1:30] Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:00 [2:00] Orin 7
Ọ̀sán
1:10 [2:40] Ohùn Orin
1:20 [2:50] Orin 54 àti Àdúrà
1:30 [3:00] Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Kí Ni Ìgbàgbọ́, Báwo La Ṣe Lè Fi Hàn Pé A Nígbàgbọ́?
2:00 [3:30] Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:30 [4:00] Orin 30 àti Ìfilọ̀
2:40 [4:10] Àpínsọ Àsọyé: ‘Mú Ẹ̀ṣẹ̀ Tó Máa Ń Wé Mọ́ Wa Pẹ̀lú Ìrọ̀rùn Kúrò’
Jèhófà Máa Mú Ìwà Búburú Kúrò
Jèhófà Máa Pèsè Àwọn Ohun Kòṣeémáàní fún Wa
Jèhófà Máa Jí Àwọn Òkú Dìde
3:40 [5:10] Ìgbàgbọ́ Tó Jinlẹ̀ Ń Mú Èrè Wá
4:15 [5:45] Orin 43 àti Àdúrà
a Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé tó bá jẹ́ ọjọ́ Sátidé “Gbálùúmọ́”