Àpéjọ Àyíká Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ 2017
Ẹṣin Ọ̀rọ̀: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn!—Mát. 22:37.
Òwúrọ̀
9:40 [11:30]a Ohùn Orin
9:50 [11:40] Orin 50 àti Àdúrà
10:00 [11:50] Máa Rántí Àṣẹ Tó Tóbi Jù Lọ
10:15 [12:05] Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run, Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé
10:30 [12:20] Kọ́ Àwọn Ẹlòmíì Láti “Nífẹ̀ẹ́ Orúkọ Jèhófà”
10:55 [12:45] Orin 112 àti Ìfilọ̀
11:05 [12:55] Ẹni Tí Ó Bá Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run Ní Láti Máa Nífẹ̀ẹ́ Arákùnrin Rẹ̀ Pẹ̀lú”
11:35 [1:25] Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:05 [1:55] Orin 34
Ọ̀sán
1:20 [2:40] Ohùn Orin
1:30 [2:50] Orin 73
1:35 [2:55] Ìrírí
1:45 [3:05] Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:15 [3:35] Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Láti Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà
2:30 [3:50] Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Fi Hàn Pé Jèhófà Ni Ọ̀rẹ́ Tẹ́ Ẹ Fẹ́ràn Jù
2:45 [4:05] Orin 106 àti Ìfilọ̀
2:55 [4:15] Má Ṣe Fi “Ìfẹ́ Tí Ìwọ Ní ní Àkọ́kọ́” Sílẹ̀
3:55 [5:15] Orin 3 àti Àdúrà
a Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé tó bá jẹ́ ọjọ́ Sátidé “Gbálùúmọ́”