ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • th ẹ̀kọ́ 16 ojú ìwé 19
  • Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Gbéni Ró Kó sì Ṣàǹfààní

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Gbéni Ró Kó sì Ṣàǹfààní
  • Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Sọ Ohun Tó Ń Gbéni Ró Tó Sì Ṣàǹfààní
    Jàǹfààní Nínú Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run
  • Ìtara
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
  • Sọ Bí Ọ̀rọ̀ Rẹ Ṣe Wúlò
    Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
Àwọn Míì
Tẹra Mọ́ Kíkàwé Àti Kíkọ́ni
th ẹ̀kọ́ 16 ojú ìwé 19

Ẹ̀KỌ́ 16

Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Gbéni Ró Kó sì Ṣàǹfààní

Ẹsẹ Bíbélì tí a tọ́ka sí

Jóòbù 16:5

KÓKÓ PÀTÀKÌ: Sọ ohun tó máa yanjú ìṣòro, tó sì ń fini lọ́kàn balẹ̀.

BÓ O ṢE LÈ ṢE É:

  • Ní èrò tó dára nípa àwọn tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ. Gbà pé ohun tí Jèhófà fẹ́ ni àwọn onígbàgbọ́ bíi tìẹ fẹ́ ṣe. Tó o bá tiẹ̀ máa fún wọn ní ìmọ̀ràn, kọ́kọ́ gbóríyìn fún wọn látọkàn wá láwọn ìgbà tó bá yẹ bẹ́ẹ̀.

    Àwọn àbá

    Má ṣe fi ìkanra sọ̀rọ̀, ńṣe ni kó o fi ìfẹ́ bá wọn sọ̀rọ̀. Rẹ́rìn-ín músẹ́, kó o lè fi wọ́n lọ́kàn balẹ̀.

  • Má sọ̀rọ̀ púpọ̀ nípa ohun tí kò dáa. Tó o bá fẹ́ fi ohun tí kò dáa ṣàlàyé nǹkan pàtàkì nìkan ni kó o sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀. Ohun tó ṣàǹfààní ló yẹ kí ọ̀rọ̀ rẹ dá lé.

  • Lo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run bó ṣe yẹ. Sọ̀rọ̀ nípa àwọn nǹkan tí Jèhófà ti ṣe, àwọn nǹkan tó ń ṣe báyìí àtàwọn nǹkan tó máa ṣe fún aráyé lọ́jọ́ iwájú. Sọ ohun tó máa mú kí àwọn tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ ní ìrètí àti ìgboyà.

LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Máa wo ẹnì kọ̀ọ̀kan bíi pé ó ṣì máa di onígbàgbọ́ bíi tìẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́