Má Ṣojo!
ÒWÚRỌ̀
9:30 Ohùn Orin
9:40 Orin 73 àti Àdúrà
9:50 Jèhófà Ni Kì Í Jẹ́ Ká Ṣojo
10:05 Àpínsọ Àsọyé: Jẹ́ Aláìṣojo Bíi Ti . . .
Énọ́kù
Mósè
Jèhóṣáfátì
Pétérù
11:05 Orin 69 àti Ìfilọ̀
11:15 Ẹ Mọ́kàn Le Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù
11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:00 Orin 48
Ọ̀SÁN
1:10 Ohùn Orin
1:20 Orin 63 àti Àdúrà
1:30 Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Pinnu Pé Ìsìn Tòótọ́ Lo Máa Ṣe
2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:30 Orin 76 àti Ìfilọ̀
2:40 Àpínsọ Àsọyé: Jẹ́ Aláìṣojo Bíi Ti Kristi Táwọn Èèyàn Bá Ń Fúngun Mọ́ Ẹ
Nínú Ìdílé
Nílé Ìwé
Níbi Iṣẹ́
Ní Àdúgbò
3:40 Jèhófà Máa San Ẹ́ Lẹ́san “Ńláǹlà” Tó Ò Bá Ṣojo
4:15 Orin 119 àti Àdúrà