“ÌFẸ́ Ń GBÉNI RÓ”
ÒWÚRỌ̀
9:30 Ohùn Orin
9:40 Orin 90 àti Àdúrà
9:50 “Ìmọ̀ Máa Ń Gbéra Ga, Àmọ́ Ìfẹ́ Ń Gbéni Ró”
10:05 Àpínsọ Àsọyé: Wọ́n Gbé Àwọn Míì Ró
Bánábà
Pọ́ọ̀lù
Dọ́káàsì
11:05 Orin 79 àti Ìfilọ̀
11:15 Máa Fìfẹ́ Hàn Sáwọn Èèyàn Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù
11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:00 Orin 52
Ọ̀SÁN
1:10 Ohùn Orin
1:20 Orin 107 àti Àdúrà
1:30 Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Báwo Ni Ìfẹ́ Tó Jinlẹ̀ Ṣe Ń Gbé Òtítọ́ Lárugẹ?
2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:30 Orin 101 àti Ìfilọ̀
2:40 Àpínsọ Àsọyé: Mú Kí Ìjọ Máa Dàgbà Sí I
Nífẹ̀ẹ́ Òtítọ́ Bíbélì
Mọyì Ọgbọ́n Tó Wà Nínú Òfin Ọlọ́run
Máa Gbé Àwọn Ará Ró
3:40 “Ẹ Máa Fi Ìfẹ́ Ṣe Gbogbo Ohun Tí Ẹ Bá Ń Ṣe”
4:15 Orin 105 àti Àdúrà