ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 155
  • Orísun Ayọ̀ Wa

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Orísun Ayọ̀ Wa
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìdùnnú​—Ànímọ́ Rere Tí Ọlọ́run Ń Fúnni
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Ẹ Yin Ọba Tuntun Tó Jẹ Lórí Ayé
    Kọrin sí Jèhófà
  • Sọ Òtítọ́ Di Tìrẹ
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Sọ Òtítọ́ Di Tìrẹ
    Kọrin sí Jèhófà
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 155

ORIN 155

Orísun Ayọ̀ Wa

Bíi Ti Orí Ìwé

(Sáàmù 16:11)

  1. 1. Àwọn ìràwọ̀ lọ salalu lójú ọ̀run.

    Bójúmọ́ bá sì ti wá mọ́,

    Oòrùn á tún yọ.

    O dá ilẹ̀ àti omi,

    Gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ

    ló ń mú inú rẹ dùn.

    (ÈGBÈ)

    Inú wa ń dùn sí iṣẹ́ rẹ,

    A sì ń wàásù ìhìn rere,

    Ayé tuntun ti dé tán.

    A mọ̀ pé o nífẹ̀ẹ́ wa gan-an,

    Èyí ló ń múnú wa dùn jù.

    Jèhófà, Ọlọ́run wa

    Lorísun ayọ̀ wa.

  2. 2. Jèhófà, ọ̀pọ̀ nǹkan lò ń ṣe

    Tó ń fún wa láyọ̀.

    A lè gbọ́ràn, a lè ríran

    A tún lè ronú.

    Èrò rere lo ní sí wa,

    O fẹ́ ká wà láàyè láéláé,

    O fẹ́ ká láyọ̀.

    (ÈGBÈ)

    Inú wa ń dùn sí iṣẹ́ rẹ,

    A sì ń wàásù ìhìn rere,

    Ayé tuntun ti dé tán.

    A mọ̀ pé o nífẹ̀ẹ́ wa gan-an,

    Èyí ló ń múnú wa dùn jù.

    Jèhófà, Ọlọ́run wa

    Lorísun ayọ̀ wa.

    (ÀSOPỌ̀)

    Ikú ìrúbọ Ọmọ rẹ

    Ló ń jẹ́ ká láyọ̀.

    Ẹ̀bùn yìí ló jẹ́ ká ní ìrètí

    Ayọ̀ tí kò lópin.

    (ÈGBÈ)

    Inú wa ń dùn sí iṣẹ́ rẹ

    A sì ń wàásù ìhìn rere,

    Ayé tuntun ti dé tán.

    A mọ̀ pé o nífẹ̀ẹ́ wa gan-an

    Èyí ló ń múnú wa dùn jù.

    Jèhófà, Ọlọ́run wa

    Lorísun ayọ̀ wa.

    (ÈGBÈ)

    Inú wa ń dùn sí iṣẹ́ rẹ

    A sì ń wàásù ìhìn rere,

    Ayé tuntun ti dé tán.

    A mọ̀ pé o nífẹ̀ẹ́ wa gan-an

    Èyí ló ń múnú wa dùn jù.

    Jèhófà, Ọlọ́run wa

    Lorísun ayọ̀ wa.

(Tún wo Sm. 37:4; 1 Kọ́r. 15:28.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́