‘Máa Retí Jèhófà’
Àárọ̀
9:30 Ohùn Orin
9:40 Orin 88 àti Àdúrà
9:50 Báwo La Ṣe Lè Máa “Retí Jèhófà”?
10:05 Àpínsọ Àsọyé: Fara Wé Àwọn Tó Retí Jèhófà
• Hábákúkù
• Jòhánù
• Ánà
11:05 Orin 142 àti Ìfilọ̀
11:15 Kí Ló Ń Dá Ẹ Dúró Láti Ṣe Púpọ̀ Sí I?
11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi
12:00 Orin 28
Ọ̀sán
1:10 Ohùn Orin
1:20 Orin 54 àti Àdúrà
1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Kí Nìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì Pé Ká Ní Sùúrù?
2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́
2:30 Orin 143 àti Ìfilọ̀
2:40 Àpínsọ Àsọyé: Máa Retí Jèhófà . . .
• Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé O Dá Wà
• Tó O Bá Ṣàṣìṣe
• Tí Nǹkan Bá Ń Lọ Dáadáa Fáwọn Ẹni Burúkú
3:40 “Èrè Wà fún Olódodo”
4:15 Orin 140 àti Àdúrà