ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp16 No. 4 ojú ìwé 16
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2016
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé àwọn èèyàn ló dá ẹ̀sìn sílẹ̀?
  • Ṣé ó pọndandan kéèyàn wà nínú ìsìn kan?
  • Ìsìn
    Jí!—2014
  • Ṣé Ó Pọn Dandan Kéèyàn Máa Dara Pọ̀ Mọ́ Ẹ̀sìn Kan Pàtó?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ṣíṣe Isin Mimọgaara fun Lilaaja
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
  • Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mọ Ìsìn Tòótọ́?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2016
wp16 No. 4 ojú ìwé 16
Ìdílé kan ń wo onírúurú àwọn ilé ìjọsìn

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ṣé àwọn èèyàn ló dá ẹ̀sìn sílẹ̀?

ÀWỌN KAN GBÀ GBỌ́ PÉ àwọn èèyàn ló bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe ẹ̀sìn; àwọn míì sì gbà pé Ọlọ́run máa ń lo ẹ̀sìn láti fa àwọn èèyàn sún mọ́ ara rẹ̀. Kí lèrò rẹ?

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

“Ọ̀nà ìjọsìn tí ó mọ́, tí ó sì jẹ́ aláìlẹ́gbin ní ojú ìwòye Ọlọ́run àti Baba wa ni èyí.” (Jákọ́bù 1:27) Èyí fi hàn pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ìjọsìn tí ó mọ́ ti wá.

KÍ LÀWỌN NǸKAN MÍÌ TÍ BÍBÉLÌ SỌ?

  • Kí ìsìn kan tó lè múnú Ọlọ́run dùn, ó gbọ́dọ̀ gbé ẹ̀kọ́ rẹ̀ lórí òtítọ́ tó wà nínú Bíbélì.—Jòhánù 4:23, 24.

  • Ẹ̀sìn tí wọ́n bá gbé karí èrò èèyàn kì í ṣe ẹ̀sìn gidi. —Máàkù 7:7, 8.

Ṣé ó pọndandan kéèyàn wà nínú ìsìn kan?

KÍ NI ÌDÁHÙN RẸ?

  • Bẹ́ẹ̀ ni

  • Bẹ́ẹ̀ kọ́

  • Mi ò mọ̀

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

“Ẹ sì jẹ́ kí a gba ti ara wa rò lẹ́nì kìíní-kejì láti ru ara wa sókè sí ìfẹ́ àti sí àwọn iṣẹ́ àtàtà, kí a má máa kọ ìpéjọpọ̀ ara wa sílẹ̀.” (Hébérù 10:24, 25) Ọlọ́run fẹ́ kí àwọn tó ń jọ́sìn rẹ̀ máa pé jọ gẹ́gẹ́ bí àwùjọ kan tó wà létòletò.

KÍ LÀWỌN NǸKAN MÍÌ TÍ BÍBÉLÌ SỌ?

  • Ìgbàgbọ́ àwọn tó ń ṣe ẹ̀sìn kan náà gbọ́dọ̀ bára mu.—1 Kọ́ríńtì 1:10, 11.

  • Àwọn tó ń ṣe ẹ̀sìn tí Ọlọ́run tẹ́wọ́ gbà gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹgbẹ́ ará kan tó kárí ayé.—1 Pétérù 2:17.

Fún ìsọfúnni síwájú sí i, ka orí 15 nínú ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é

Ó tún wà lórí ìkànnì www.jw.org/yo

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́