ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp18 No. 2 ojú ìwé 16
  • “Àwọn Ọlọ́kàn Tútù Ni Yóò Ni Ilẹ̀ Ayé”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Àwọn Ọlọ́kàn Tútù Ni Yóò Ni Ilẹ̀ Ayé”
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àǹfààní Tí Wàá Rí Tó O Bá Mọ Òtítọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2020
  • O Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2019
  • Ohun Tó O Bá Ṣe Láá Pinnu Bọ́jọ́ Ọ̀la Ẹ Ṣe Máa Rí
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2021
  • Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la?
    Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la?
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2018
wp18 No. 2 ojú ìwé 16
Ìdílé kan

“Àwọn Ọlọ́kàn Tútù Ni Yóò Ni Ilẹ̀ Ayé”

Ọ̀pọ̀ nínú wa ló ti rí bí àwọn èèyàn ṣe ń gbé ẹ̀bi fún aláre tí wọ́n sì ń gbé àre fún ẹlẹ́bi, a tún ń rí bí àwọn ẹni ibi ṣe ń fìyà jẹ aláìmọwọ́mẹsẹ̀. Ṣé ìgbà kan tiẹ̀ ń bọ̀ tí ìwà ìrẹ́jẹ àti ìwà ìkà kò ní sí mọ́?

Nínú Bíbélì, Sáàmù 37 dáhùn ìbéèrè yìí, ó sì fún wa láwọn ìmọ̀ràn tó wúlò gan-an. Gbọ́ ohun tó sọ nípa àwọn ìbéèrè pàtàkì yìí.

  • Kí ló yẹ ká ṣe táwọn èèyàn bá ń ni wá lára?​—Ẹsẹ 1 àti 2.

  • Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn ẹni burúkú? ​—Ẹsẹ 10.

  • Báwo ni ọjọ́ ọ̀la àwọn tó ń hùwà rere ṣe máa rí?​—Ẹsẹ 11 àti 29.

  • Kí ló yẹ ká máa ṣe báyìí?​—Ẹsẹ 34.

Ohun tí Ọlọ́run sọ ní Sáàmù 37 jẹ́ kó ṣe kedere pé ọ̀la ń bọ̀ wá dára fún àwọn tó ‘ní ìrètí nínú Jèhófà, tí wọ́n sì ń pa ọ̀nà rẹ̀ mọ́.’ Inú àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa dùn láti ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì mọ ohun tó yẹ kó o ṣe kí ìwọ àtàwọn èèyàn rẹ lè gbádùn ọjọ́ ọ̀la aláyọ̀ yẹn.

Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa àwọn nǹkan rere tí Ọlọ́run sọ pé òun máa ṣe lójọ́ iwájú, fi ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é, ó tún wà lórí ìkànnì www.jw.org/yo

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́