ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp19 No. 1 ojú ìwé 16
  • O Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • O Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ó Bìkítà fún Ẹ”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2019
  • Àǹfààní Tí Wàá Rí Tó O Bá Mọ Òtítọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2020
  • Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tó o bá ń jìyà?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2018
  • “Àwọn Ọlọ́kàn Tútù Ni Yóò Ni Ilẹ̀ Ayé”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2018
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2019
wp19 No. 1 ojú ìwé 16

O Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run

ÀWỌN KAN RÒ PÉ . . .

Kò sí bá a ṣe lè sún mọ́ Ọlọ́run, torí pé kò rí tiwa rò, ó ti jìnnà jù sí wa àti pé ẹni mímọ́ ni.

BÍBÉLÌ SỌ PÉ

Obìnrin kan ń ka Bíbélì

“Ẹ sún mọ́ Ọlọ́run, á sì sún mọ́ yín.” ​—Jémíìsì 4:8.

“Ẹ . . . kó gbogbo àníyàn yín lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, torí ó ń bójú tó yín.”​—1 Pétérù 5:7.

BÁWO LA ṢE LÈ SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN?

  • Máa bá a sọ̀rọ̀.​—Sáàmù 145:18, 19.

  • Máa fetí sí i.​—Sáàmù 32:8.

  • Máa tẹ̀ lé ìtọ́ni rẹ̀.​—Òwe 3:5, 6.

  • Má ṣe jẹ́ kó sú ẹ.​—Mátíù 7:7, 8.

Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa ọjọ́ ọ̀la tó ń fini lókàn balẹ̀ tí Ọlọ́run ṣèlérí, a rọ̀ ẹ́ pé kó o bẹ̀rẹ̀ sí í fi ìwé yìí kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é, ó sì wà lórí www.jw.org

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́