ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp19 No. 2 ojú ìwé 16
  • “Ó Bìkítà fún Ẹ”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ó Bìkítà fún Ẹ”
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • O Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2019
  • Àǹfààní Tí Wàá Rí Tó O Bá Mọ Òtítọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2020
  • Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tó o bá ń jìyà?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2018
  • Ǹjẹ́ Ìyà Lè Dópin?
    Ǹjẹ́ Ìyà Lè Dópin?
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2019
wp19 No. 2 ojú ìwé 16

“Ó Bìkítà fún Ẹ”

Ọ̀dọ́bìnrin kan rẹ́rìn-ín músẹ́, ó sì ń rìn gba àárín èèyàn púpọ̀ kọjá

Kódà tí àwọn míì bá tiẹ̀ já ẹ kulẹ̀, ẹnì kan wà tí kò ní fi ẹ́ sílẹ̀ láé. Ta ni ẹni náà?

Ọba Dáfídì sọ pé: “Kódà, tí bàbá mi àti ìyá mi bá kọ̀ mí sílẹ̀, Jèhófà fúnra rẹ̀ yóò tẹ́wọ́ gbà mí.”​—Sáàmù 27:10.

Jèhófà jẹ́ “Baba àánú oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ àti Ọlọ́run ìtùnú gbogbo, ẹni tó ń tù wá nínú nínú gbogbo àdánwò wa.”​—2 Kọ́ríńtì 1:3, 4.

“Ẹ máa kó gbogbo àníyàn yín lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, torí ó ń bójú tó yín.”​—1 Pétérù 5:7.

Kó o lè mọ bí Ọlọ́run ṣe máa ràn ẹ́ lọ́wọ́, wo ẹ̀kọ́ 08 nínú ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é, ó sì wà lórí ìkànnì www.jw.org/yo

Tó o bá fẹ́ mọ púpọ̀ sí i nípa bó o ṣe lè sún mọ́ Ọlọ́run, wo ẹ̀kọ́ 08 nínú ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é, ó sì wà lórí ìkànnì www.jw.org/yo

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́