ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 July ojú ìwé 8
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Iṣẹ́ Ìsìn Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Iṣẹ́ Ìsìn Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìṣètò Olùrànlọ́wọ́ Aṣáájú Ọ̀nà
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1997
  • Ṣé Ọ̀nà Àtiṣe Aṣáájú Ọ̀nà Ti Ṣí Sílẹ̀ fún Ọ Báyìí?
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1999
  • Àkókò Ìṣe Ìrántí—Àkókò Tí Ìgbòkègbodò Tẹ̀mí Wa Máa Ń Pọ̀ Sí I
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2005
  • Ṣé A Óò Ṣe É Lẹ́ẹ̀kan Sí I?—Ìpè Mìíràn fún Àwọn Aṣáájú Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1998
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 July ojú ìwé 8

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Iṣẹ́ Ìsìn Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé

Àwọn aṣáájú-ọ̀nà méjì ń wàásù fún ọkùnrin kan

Kéèyàn tó lè ṣe aṣáájú-ọ̀nà déédéé, ó gbọ́dọ̀ ní ètò tó dáa. O lè ṣe iṣẹ́ aṣáájú-ọ̀nà tó o bá lè máa ní wákàtí méjìdínlógún [18] lọ́sẹ̀, wàá sì tún ráyè fún àwọn nǹkan míì! Kódà, wákàtí rẹ ṣì lè máa pé táwọn nǹkan àìròtẹ́lẹ̀ bá tiẹ̀ yọjú, irú bí àìsàn tàbí ojú ọjọ́ tí kò dáa. Ìtòlẹ́sẹẹsẹ tó wà nínú àpilẹ̀kọ yìí fi hàn bí àwọn akéde ṣe lè ṣe aṣáájú-ọ̀nà, bóyá wọ́n ń fi àkókò díẹ̀ ṣiṣẹ́ tàbí wọ́n ń ṣiṣẹ́ fún àkókò tó pọ̀ títí kan àwọn tó ní àìlera. Tẹ́ ẹ bá ṣe àwọn àyípadà kan, ẹnì kan nínú ìdílé yín lè bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ aṣáájú-ọ̀nà lóṣù September. Ó máa dáa tẹ́ ẹ bá lè jíròrò rẹ̀ nígbà ìjọsìn ìdílé yín tó kàn.

ÀKÓKÒ DÍẸ̀ NI MO FI Ń ṢIṢẸ́

Monday

IṢẸ́

Tuesday

IṢẸ́

Wednesday

IṢẸ́

Thursday

wákàtí 6

Friday

wákàtí 6

Saturday

wákàtí 4

Sunday

wákàtí 2

ÀKÓKÒ TÓ PỌ̀ NI MO FI Ń ṢIṢẸ́

Monday

wákàtí 2

Tuesday

wákàtí 2

Wednesday

ÌPÀDÉ ÀÁRÍN Ọ̀SẸ̀

Thursday

wákàtí 2

Friday

wákàtí 2

Saturday

wákàtí 6

Sunday

wákàtí 4

MO NÍ ÀÌLERA

Monday

SINMI

Tuesday

wákàtí 3

Wednesday

wákàtí 3

Thursday

wákàtí 3

Friday

wákàtí 3

Saturday

wákàtí 3

Sunday

wákàtí 3

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́