ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 October ojú ìwé 7
  • “Tọ́ Ọmọdékùnrin Ní Ọ̀nà Tí Yóò Tọ̀”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Tọ́ Ọmọdékùnrin Ní Ọ̀nà Tí Yóò Tọ̀”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Mímọrírì Ìdí Tá A Fi Ń Báni Wí
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Ẹ̀yin Òbí—ẹ Máa Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Tìfẹ́tìfẹ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Bí O Ṣe Lè Bá Àwọn Ọmọ Rẹ Wí
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 October ojú ìwé 7

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÒWE 22-26

“Tọ́ Ọmọdékùnrin Ní Ọ̀nà Tí Yóò Tọ̀”

Ìyá kan ń kàwé fún ọmọbìnrin rẹ̀, bàbá kan àti ọmọkùnrin rẹ̀ jọ ń mọ ìkòkò

Ìwé Òwe ní ọ̀pọ̀ ìmọ̀ràn tó wúlò gan-an fún àwọn òbí. Bí àpẹẹrẹ, ibi tí wọ́n bá tẹ ẹ̀ka igi kan sì nígbà tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ń hù ló máa pinnu bí igi náà ṣe máa rí tó bá dàgbà. Bákan náà ni àwọn ọmọ tí wọ́n tọ́ dáadáa ṣe sábà máa ń bá a lọ láti sin Jèhófà nígbà tí wọ́n bá dàgbà.

22:6

  • Ẹnì kan ń de ẹ̀ka igi mọ́ igi kan

    Ó máa ń gba ìsapá àti ọ̀pọ̀ àkókò kéèyàn tó lè tọ́ ọmọ kan dáadáa

  • Àwọn òbí gbọ́dọ̀ jẹ́ àpẹẹrẹ rere fún àwọn ọmọ wọn, kí wọ́n fara balẹ̀ kọ́ wọn, kí wọ́n gbà wọ́n níyànjú, kí wọ́n fún wọn níṣìírí, kí wọ́n sì máa bá wọn wí

22:15

  • Ìbáwí jẹ́ ìdálẹ́kọ̀ọ́ tó máa ń yí èrò àti ìṣe ẹni pa dà sí rere

  • Kì í ṣe irú ìbáwí kan náà ló máa ń wúlò fún gbogbo ọmọ

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́