ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 December ojú ìwé 7
  • Ilẹ̀ Ayé Yóò Kún fún Ìmọ̀ Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ilẹ̀ Ayé Yóò Kún fún Ìmọ̀ Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • O Lè Ní Ọjọ́-Ọ̀la Aláyọ̀!
    Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun
  • “Àá Pàdé ní Párádísè!”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Ǹjẹ́ Ẹ Ti Para Dà?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Párádísè Ti Padà Bọ̀ Sípò!
    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà—Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kìíní
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 December ojú ìwé 7

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 11-16

Ilẹ̀ Ayé Yóò Kún fún Ìmọ̀ Jèhófà

Ọmọ kékeré kan ń bá àwọn ẹranko igbó ṣeré ní Párádísè

11:6-9

Bí àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ṣẹ sáwọn ọmọ Ísírẹ́lì lára

  • Kò sí ìdí fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì láti bẹ̀rù àwọn ẹranko ẹhànnà tàbí àwọn ẹhànnà èèyàn nígbà tí wọ́n ń pa dà sí ìlú wọn láti ìgbèkùn ní Bábílónì àti nígbà tí wọ́n dé ìlú wọn.​—Ẹsr 8:21, 22

Bí àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe kàn wá lóde òní

  • Ìmọ̀ Jèhófà ti mu káwọn èèyàn yí ìwà wọn pa dà sí rere. Àwọn kan tí wọ́n jẹ́ oníjàgídíjàgan tẹ́lẹ̀ ti wá di èèyàn jẹ́jẹ́. Ìmọ̀ Ọlọ́run ti mú ká wà nínú Párádísè tẹ̀mí tó kárí ayé

Bí àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe máa ṣẹ lọ́jọ́ iwájú

  • Ayé máa yí pa dà di Párádísè, àlááfíà á sì wà níbi gbogbo bí Ọlọ́run ṣe fẹ́ kó rí láti ìpilẹ̀ṣẹ̀. Kò sí ẹ̀dá kankan tó máa dẹ́rù bà wá, ì báà jẹ́ èèyàn tàbí ẹranko

Ìmọ̀ Ọlọ́run yí Pọ́ọ̀lù pa dà sí rere

  • Nígbà tó ṣì jẹ́ Farisí, ìwà ẹhànnà ló kún ọwọ́ rẹ̀.​—1Ti 1:13

  • Ìmọ̀ Ọlọ́run tó ní ló jẹ́ kó yíwà pa dà.​—Kol 3:8-10

Onínúfùfù ni àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù tẹ́lẹ̀ kó tó yíwà padà di onínútútù
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́