ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 January ojú ìwé 3
  • “Ọba Kan Yóò Jẹ fún Òdodo”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ọba Kan Yóò Jẹ fún Òdodo”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Kíyè Sí Ara Yín àti Gbogbo Agbo”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • “Ẹ Máa Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo Ọlọ́run Tí Ń bẹ Lábẹ́ Àbójútó Yín”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • “Ẹ Máa Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo Ọlọ́run”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • “Má Bẹ̀rù, Agbo Kékeré”
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 January ojú ìwé 3

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 29-33

“Ọba Kan Yóò Jẹ fún Òdodo”

Jésù tó jẹ́ Ọba wa, fún wa ní “àwọn ọmọ aládé,” ìyẹn àwọn alàgbà, tó ń bójú tó agbo Ọlọ́run

32:1-3

  • Wọ́n dà bí “ibi ìfarapamọ́sí kúrò lọ́wọ́ ẹ̀fúùfù,” torí pé wọ́n ń dáàbò bo agbo lọ́wọ́ inúnibíni àti ìrẹ̀wẹ̀sì tó dà bí ìjì líle

  • Wọ́n dà “bí àwọn ìṣàn omi ní ilẹ̀ aláìlómi,” ní ti pé wọ́n ń pèsè ìtura fún àwọn tí òǹgbẹ tẹ̀mí ń gbẹ. Ọ̀nà tí wọ́n ń gbà ṣe bẹ́ẹ̀ ni pé wọ́n ń kọ́ wọn ní ẹ̀kọ́ òtítọ́ tí kò lábùlà

  • Wọ́n dà “bí òjìji àpáta gàǹgà ní ilẹ̀ gbígbẹ táútáú,” torí pé wọ́n ń ran agbo Ọlọ́run lọ́wọ́ láti rí ìtura àti ìtọ́sọ́nà tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run

    Ọkùnrin kan láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì sá pamọ́ nítorí ẹ̀fúùfù, ó mu omi látinú ìṣàn omi, ó sì ń sinmi lábẹ́ òjìji àpáta gàǹgà
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́