ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 February ojú ìwé 3
  • Kristi Jìyà fún Wa

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kristi Jìyà fún Wa
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìránṣẹ́ Jèhófà Tí Wọ́n ‘Gún Nítorí Ìrélànàkọjá Wa’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Jèhófà Gbé Mèsáyà Ìránṣẹ́ Rẹ̀ Ga
    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà—Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kejì
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • Kíkojú Ìpènijà Ìdúróṣinṣin
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 February ojú ìwé 3

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | AÍSÁYÀ 52-57

Kristi Jìyà fún Wa

“A tẹ́ńbẹ́lú rẹ̀, àwọn ènìyàn sì yẹra fún un . . . Àwa fúnra wa kà á sí ẹni tí ìyọnu bá, ẹni tí Ọlọ́run kọlù, tí ó sì ṣẹ́ níṣẹ̀ẹ́”

53:​3-5

  • Àwọn èèyàn tẹ́ńbẹ́lú Jésù, wọ́n sì fẹ̀sùn kàn án pé ó jẹ́ asọ̀rọ̀-òdì. Àwọn kan gbà pé Ọlọ́run ló ń fìyà jẹ ẹ́, bí ìgbà tó fi àìsàn burúkú kọ lù ú

    Jésù pinnu láti jẹ́ adúróṣinṣin bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó mọ̀ pé òun gbọ́dọ̀ jìyà

“Jèhófà tìkára rẹ̀ ní inú dídùn sí títẹ̀ ẹ́ rẹ́, . . . ohun tí Jèhófà ní inú dídùn sí yóò sì kẹ́sẹ járí ní ọwọ́ rẹ̀”

53:10

  • Kò sí àní-àní pé ó máa dun Jèhófà wọra nígbà tó rí ìyà tí wọ́n fi jẹ Ọmọ rẹ̀, tí wọ́n sì pa á. Àmọ́ inú rẹ̀ dùn pé Jésù jẹ́ olóòótọ́ láìkù síbi kan. Ikú Jésù tún fi hàn pé irọ́ gbuu ni Sátánì pa pé àwa ìránṣẹ́ Ọlọ́run ò lè jẹ́ adúróṣinṣin sí i. Ó sì máa jẹ́ kí àwọn tó ronú pìwà dà rí ojúure Ọlọ́run. Ó sì tún ṣàṣeparí “ohun tí Jèhófà ní inú dídùn sí”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́