ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 November ojú ìwé 8
  • Ẹ̀kọ́ Tó Wà Nínú Ìwé Jónà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ̀kọ́ Tó Wà Nínú Ìwé Jónà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ó Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àwọn Àṣìṣe Rẹ̀
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
  • Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àwọn Àṣìṣe Rẹ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Ó Kọ́gbọ́n Látinú Àṣìṣe Ara Ẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Jona Kọ́ Nípa Àánú Jehofa
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 November ojú ìwé 8

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ẹ̀kọ́ Tó Wà Nínú Ìwé Jónà

Jèhófà mú kí wọ́n kọ ìtàn ìgbésí ayé àwọn ọkùnrin àti obìnrin tó ní ìgbàgbọ́ sínú Bíbélì ọ̀rọ̀ rẹ̀, kí a lè rí ẹ̀kọ́ gidi kọ́ lára wọn. (Ro 15:4) Kí lo rí kọ́ nínú ìwé Jónà? Wo fídíò náà Ìjọsìn Ìdílé: Jónà​—Kọ́ Bí O Ṣe Lè Jẹ́ Aláànú Bíi Ti Jèhófà, kó o sì dáhùn àwọn ìbéèrè yìí:

  • Àwọn ìṣòro wo ni àwọn akéde mẹ́tẹ̀ẹ̀ta tó wà nínú fídíò yẹn ní?

  • Báwo ni ìwé Jónà ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ nígbà tí wọ́n bá bá wa wí tàbí tá a pàdánù àwọn àǹfààní iṣẹ́ ìsìn kan? (1Sa 16:7; Jon 3:1, 2)

  • Báwo ni ìwé Jónà ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti ní èrò tó dáa nípa ìpínlẹ̀ ìwàásù wa? (Jon 4:11; Mt 5:7)

  • Báwo ni àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Jónà ṣe lè tù wá nínú nígbà tá a bá ń ṣàìsàn tó le koko? (Jon 2:1, 2, 7, 9)

  • Ẹ̀kọ́ wo lo kọ́ nínú fídíò yìí nípa bó ti ṣe pàtàkì tó pé ká máa ka Bíbélì ká sì máa ṣàṣàrò lé e lórí?

Arákùnrin kan rẹ̀wẹ̀sì torí ó pàdánù àǹfààní iṣẹ́ ìsìn kan; arábìnrin kan gbà pé àwọn èèyàn ò ní tẹ́tí sí òun lóde ẹ̀rí; dókítà sọ ọ̀rọ̀ kan fún arábìnrin kan tó mú kí inú rẹ̀ bà jẹ́
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́