ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 December ojú ìwé 6
  • Ṣé Ìgbéyàwó Rẹ Ń Múnú Jèhófà Dùn?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ìgbéyàwó Rẹ Ń Múnú Jèhófà Dùn?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Kórìíra Ìwà Àdàkàdekè
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • Ohun Tó Yẹ Kó o Ṣe Kó o Lè Ní Ìdílé Tó Ń múnú Ọlọ́run Dùn
    Máa Fi Ọjọ́ Jèhófà Sọ́kàn
  • Ẹ Jẹ́ Olóòótọ́ sí Ara Yín
    Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀
  • Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Ṣètò Ìgbéyàwó?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 December ojú ìwé 6
Ọmọ Ísírẹ́lì kan fi ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁLÁKÌ 1-4

Ṣé Ìgbéyàwó Rẹ Ń Múnú Jèhófà Dùn?

2:13-16

  • Nígbà ayé Málákì, ìkọ̀sílẹ̀ wọ́pọ̀ láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, èyí sì máa ńjẹ́ lórí ẹ̀sùn tí kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀. Jèhófà kò tẹ́wọ́ gba ìjọsìn àwọn tó ńṣe àdàkàdekè sí ọkọ tàbí aya wọn

  • Jèhófà bù kún àwọn tó ńṣìkẹ́ ọkọ tàbí aya wọn

Lónìí, báwo ni àwọn tọkọtaya ṣe lè jẹ́ olóòótọ́ sí ara wọn nínú...

  • èrò wọn?

  • ohun tí wọ́n ńwò?

  • ọ̀rọ̀ wọn?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́