ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 January ojú ìwé 7
  • Jésù Mú Kí Ara Tù Wá

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Mú Kí Ara Tù Wá
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Àjàgà Mi Jẹ́ Ti Inúrere Ẹrù Mi Sì Fúyẹ́”
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
  • Oògùn Ajẹ́bíidán Fún Másùnmáwo
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
  • Mátíù 11:28-30—“Ẹ Wá Sọ́dọ̀ Mi . . . Èmi Yóò Fún Yín Ní Ìsinmi”
    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì
  • “Ẹ Wá Sọ́dọ̀ Mi, . . . Màá sì Tù Yín Lára”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 January ojú ìwé 7

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 10-11

Jésù Mú Kí Ara Tù Wá

11:28-30

Àwòrán obìnrin kan tó gbé àjàgà láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì

“Àjàgà mi jẹ́ ti inú rere”

Torí pé Jésù jẹ́ káfíńtà, ó mọ bí wọ́n ṣe máa ń ṣe àjàgà, tí wọ́n á fi aṣọ tàbí awọ wé e kí ó lè tura fún ẹni tó bá gbé e. Nígbà tá a ṣe ìrìbọmi, a di ọmọ ẹ̀yìn Jésù, a sì ti gba àjàgà rẹ̀, àtìgbà náà la ti ń ṣe iṣẹ́ ńlá tó gbé fún wa, iṣẹ́ náà ń mára tuni, ó sì máa ń yọrí sí ọ̀pọ̀ ìbùkún.

Àwọn ìbùkún wo lo ti rí látìgbà tó o ti gba àjàgà Jésù?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́