ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 April ojú ìwé 5
  • Jésù Ṣe Ìwòsàn ní Ọjọ́ Sábáàtì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Ṣe Ìwòsàn ní Ọjọ́ Sábáàtì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ló Bófin Mu ní Sábáàtì?
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
  • Ki Ni Ohun Tí Ó Bófinmu ní Sabaati?
    Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí
  • Ṣé Ó Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Máa Pa Sábáàtì Mọ́?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Wọ́n Já Ọkà Jẹ Lọ́jọ́ Sábáàtì
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 April ojú ìwé 5
Ọkùnrin kan tọ́wọ́ ẹ̀ gbẹ hangogo wá sọ́dọ̀ Jésù

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 3-4

Jésù Ṣe Ìwòsàn ní Ọjọ́ Sábáàtì

3:1-5

Kí nìdí tí ìwà àwọn aṣáájú ẹ̀sìn Júù fi kó ẹ̀dùn ọkàn bá Jésù gidigidi? Ìdí ni pé wọ́n gbé àwọn òfin kéékèèké kalẹ̀, èyí tó mú kí pípa òfin Sábáàtì mọ́ di ẹrù ìnira. Bí àpẹẹrẹ, wọ́n sọ pé ẹ̀ṣẹ̀ ni kéèyàn pa kòkòrò mùjẹ̀mùjẹ̀. Ìgbà tí ẹ̀mí ẹnì kan bá wà nínú ewu ni wọ́n tó lè ṣe ìwòsàn fún un. Èyí fi hàn pé wọn ò ní ṣe ìwòsàn ẹni tí egungun ẹ̀ kán tàbí tó fi ibì kan rọ́ lọ́jọ́ Sábáàtì. Ó ṣe kedere pé àwọn aṣáájú ẹ̀sìn náà kò láàánú ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ gbẹ hangogo yẹn.

BI ARA RẸ PÉ:

  • ‘Ṣé àwọn èèyàn mọ̀ mí sí ẹni tó lójú àánú àbí ẹni tó ń rin kinkin mọ́ òfin?’

  • ‘Tí mo bá rí ẹnì kan nínú ìjọ tó nílò ìrànlọ́wọ́, báwo ni mo ṣe lè fara wé bí Jésù ṣe máa ń ṣojú àánú sáwọn èèyàn débi tágbára mi bá gbé e dé?’

Àwọn alàgbà méjì ṣe ìbẹ̀wò olùṣọ́ àgùntàn sọ́dọ̀ arábìnrin kan tọ́wọ́ ẹ̀ máa ń dí àti ọmọkùnrin rẹ̀
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́