ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 April ojú ìwé 6
  • Jésù Ní Agbára Láti Jí Àwọn Èèyàn Wa Tó Kú Dìde

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Ní Agbára Láti Jí Àwọn Èèyàn Wa Tó Kú Dìde
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Arákùnrin Rẹ Máa Dìde”!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Àjíǹde Jésù—Àǹfààní Wo Ló Ṣe Wá?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
  • “Mo Ní Ìrètí Sọ́dọ̀ Ọlọ́run”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Ẹ̀kọ́ Àjíǹde Kàn Ọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 April ojú ìwé 6
Jésù jí ọmọbìnrin Jáírù dìde

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 5-6

Jésù Ní Agbára Láti Jí Àwọn Èèyàn Wa Tó Kú Dìde

5:38-42

  • Ìyá kan ń sunkún lẹ́gbẹ̀ẹ́ sàréè ọmọbìnrin rẹ̀, ó sì ń ronú nípa ìgbà tó máa jíǹde

    Tá a bá sunkún nígbà tí èèyàn wa bá kú, ìyẹn ò fi hàn pé a ò ní ìgbàgbọ́ nínú àjíǹde (Jẹ 23:2)

  • A máa túbọ̀ nígbàgbọ́ nínú àjíǹde tó ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú, tá a bá ń ronú lórí àwọn àjíǹde tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀

Ta lò ń fojú sọ́nà láti rí nígbà àjíǹde?

Báwo ló ṣe máa rí lára ẹ tẹ́ ẹ bá pa dà ríra?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́