ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 May ojú ìwé 7
  • Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìbẹ̀rù Èèyàn Dẹkùn Mú Ẹ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìbẹ̀rù Èèyàn Dẹkùn Mú Ẹ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Wọ́n Ṣe Tán Láti Wàásù Láìka Àtakò Sí
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
  • “Mo Fi Àwòṣe Lélẹ̀ fún Yín”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Ìrànlọ́wọ́ Láti Borí Ìbẹ̀rù
    Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà
  • Jésù Fẹ́ràn Àwọn Ọmọdé
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 May ojú ìwé 7

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 13-14

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìbẹ̀rù Èèyàn Dẹkùn Mú Ẹ

Kí nìdí tí àwọn àpọ́sítélì fi jẹ́ kí ìbẹ̀rù èèyàn mú wọn?

14:29, 31

  • Wọ́n dá ara wọn lójú jù. Pétérù tiẹ̀ tún ronú pé òun máa dúró ti Jésù ju àwọn àpọ́sítélì tó kù lọ

    Pétérù sẹ́ Jésù

14:32, 37-41

  • Wọn ò wà lójúfò, wọn ò sì gbàdúrà

    Àwọn àpọ́sítélì ń sùn nígbà tí Jésù ń gbàdúrà

Lẹ́yìn tí Jésù jíǹde, kí ló ran àwọn àpọ́sítélì tó ti ronú pìwà dà yìí lọ́wọ́ láti má ṣe jẹ́ kí ìbẹ̀rù èèyàn dẹkùn mú wọn, tí wọ́n sì ń wàásù láìka àtakò sí?

13:9-13

  • Wọ́n fi ìkìlọ̀ Jésù sọ́kàn, torí náà wọ́n ti wà ní ìmúrasílẹ̀ fún àtakò tàbí inúnibíni

  • Wọ́n gbára lé Jèhófà, wọ́n sì ń gbàdúrà.​—Iṣe 4:​24, 29

    Pétérù àti Jòhánù wà níwájú ìgbìmọ̀ Sànhẹ́dírìn

Irú ipò wo ló lè dán ìgboyà wa wò?

Obìnrin kan tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí wà lórí bẹ́ẹ̀dì nílé ìwòsàn, ó ń bá dókítà sọ̀rọ̀; ọmọkùnrin kan tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí wà nínú kíláàsì, kò bá wọn kí àsíá; wọ́n ń fún Ẹlẹ́rìí kan ní ìwé ìkésíni láti wá síbi àpèjẹ kan tí wọ́n fẹ́ ṣe níbi iṣẹ́ rẹ̀
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́