ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 October ojú ìwé 5
  • “Mo Fi Àwòṣe Lélẹ̀ fún Yín”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Mo Fi Àwòṣe Lélẹ̀ fún Yín”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọkùnrin Títóbilọ́lá Jù Lọ Ṣe Iṣẹ́ Rírẹlẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
  • Jésù Kọ́ Wa Láti Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Ní Ojúlówó Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • “Ẹni Rírẹlẹ̀ ní Ọkàn-Àyà Ni Èmi”
    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn”
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 October ojú ìwé 5
Jésù fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì rẹ̀

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 13-14

“Mo Fi Àwòṣe Lélẹ̀ fún Yín”

13:5, 12-15

Jésù fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì rẹ̀, ó kọ́ wọn pé kí wọ́n jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ kí wọ́n sì máa ṣe àwọn iṣẹ́ tó rẹlẹ̀ fún àwọn arákùnrin wọn.

Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ . . .

  • Arábìnrin méjì ní èdèkòyédè

    tí wàhálà tàbí èdèkòyédè bá wáyé?

  • Arákùnrin kan ń fún arákùnrin mí ì ní ìmọ̀ràn

    tí wọ́n bá fún mi nímọ̀ràn tàbí tí wọ́n bá tún ojú ìwòye mi ṣe?

  • Àwọn ará ń tún Gbọ̀ngàn Ìjọba ṣe

    tí wọ́n bá ní ká wá tún Gbọ̀ngàn Ìjọba wa ṣe?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́