ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 September ojú ìwé 6
  • Jésù Yin Baba Rẹ̀ Lógo

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jésù Yin Baba Rẹ̀ Lógo
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Gbé Òpó Igi Oró Rẹ, Kí Ó sì Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Táwọn Míì Bá Ń Yìn Ẹ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Irú Ẹni Wo Ni Jésù?
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Jésù Kristi—Míṣọ́nnárì Tó Ta Yọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 September ojú ìwé 6
Jésù yin Baba rẹ̀ lógo

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÒHÁNÙ 7-8

Jésù Yin Baba Rẹ̀ Lógo

7:15-18, 28, 29; 8:29

Gbogbo ohun tí Jésù ṣe, tó sì sọ ló fi yin Baba rẹ̀ ọ̀run lógo. Jésù fẹ́ káwọn èèyàn mọ̀ pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni gbogbo ohun tí òun ń sọ ti wá. Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé Ìwé Mímọ́ ló máa ń gbé ọ̀rọ̀ rẹ̀ kà, ó sì máa ń fa ọ̀rọ̀ yọ látinú rẹ̀ lọ́pọ̀ ìgbà. Tí wọ́n bá yin Jésù fún ohun tó ṣe, kì í gba ìyìn yẹn fún ara rẹ̀, Jèhófà ló máa ń fògo fún. Ohun tó jẹ ẹ́ lógún jù ni bó ṣe máa ṣe iṣẹ́ tí Jèhófà gbé fún un yanjú.​—Jo 17:4.

Báwo la ṣe lè fìwà jọ Jésù nígbà . . .

  • tá a bá níṣẹ́ lórí pèpéle?

  • tí wọ́n bá gbóríyìn fún wa?

  • tá a bá ń ronú nípa ohun tá a fẹ́ fi àkókò wa ṣe?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́