ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 February ojú ìwé 4
  • “Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Tirẹ̀ fún Wa”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Tirẹ̀ fún Wa”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìràpadà “Ọrẹ Pípé” Tí Baba Fún Wa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Ìràpadà—Ẹ̀bùn Tó Ṣeyebíye Jù Lọ Tí Ọlọ́run Fúnni
    Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
  • Ìràpadà Ni Ẹ̀bùn Tó Dáa Jù Lọ Tí Ọlọ́run Fún Wa
    Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
  • Máa Fi Hàn Pé O Mọyì Ìràpadà Nígbà Gbogbo
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 February ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 4-6

“Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Tirẹ̀ fún Wa”

5:8, 18, 21

Ẹ̀bùn ìràpadà tí Jèhófà fún wa ló máa jẹ́ kí orúkọ rẹ̀ di mímọ́, ó tún máa fi hàn pé Jèhófà nìkan ló lẹ́tọ̀ọ́ láti ṣàkóso ayé àti ọ̀run àti pé ìṣàkóso rẹ̀ ló dáa jù lọ. Ìràpadà ló tún jẹ́ kó ṣeé ṣe fún wa láti di ọ̀rẹ́ Jèhófà, òun náà ló máa jẹ́ kí àwọn tó bá tẹ́tí sí Ọlọ́run wà láàyè títí láé.

Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọrírì ẹ̀bùn ìràpadà yìí?

  • Ọkùnrin kan ń ṣe ìrìbọmi

    Ìyàsímímọ́ àti ìrìbọmi fi hàn pé a ní ìgbàgbọ́ nínú ìràpadà àti pé ti Jèhófà la fẹ́ ṣe

  • Àwọn arákùnrin méjì ń wàásù

    Iṣẹ́ ìwàásù Ìjọba Ọlọ́run fi hàn pé irú ìfẹ́ tí Jèhófà ní sí gbogbo èèyàn ni àwa náà ń fara wé.​—Mt 22:39; Jo 3:16

Àwọn ọ̀nà míì wo ni mo lè gbà fi hàn pé mo mọrírì ẹ̀bùn ìràpadà tí Jèhófà fún wa?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́