ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 February ojú ìwé 5
  • Ṣé Ò Ń Fojú Sọ́nà Pẹ̀lú Ìháragàgà?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ò Ń Fojú Sọ́nà Pẹ̀lú Ìháragàgà?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Dídúró Pẹ̀lú “Ìfojúsọ́nà Oníhàáragàgà”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1998
  • Jẹ́ Kí Ìrètí Tá A Ní Máa Fún Ẹ Láyọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Òmìnira Ológo fún Àwọn Ọmọ Ọlọ́run Láìpẹ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1998
  • Ẹ Máa Bá A Nìṣó ní Fífojú Sọ́nà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2015
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 February ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 7-8

Ṣé Ò Ń Fojú Sọ́nà Pẹ̀lú Ìháragàgà?

8:19-21

  • “Ìṣẹ̀dá”: aráyé tó ń fojú sọ́nà láti wà láàyè títí láé lórí ilẹ̀ ayé

  • “Ìṣípayá àwọn ọmọ Ọlọ́run”: nígbà tí àwọn ẹni àmì òróró bá dara pọ̀ mọ́ Kristi láti pa ètò àwọn nǹkan búburú Sátánì run

  • “Nítorí ìrètí”: ìlérí tí Jèhófà ṣe pé òun máa dá wa sílẹ̀ lọ́wọ́ ikú àti ẹ̀ṣẹ̀, nípasẹ̀ ikú àti àjíǹde Jésù

  • ‘Dá sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìsọdẹrú fún ìdíbàjẹ́’: ìdáǹdè lọ́wọ́ ipa tí ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú ti ní lórí wa

Ọ̀dọ́kùnrin Ẹlẹ́rìí kan ń ṣe ìdákẹ́kọ̀ọ́, ó ń dáhùn ní ìpàdé, kò fojú sílẹ̀ fún ọ̀dọ́bìnrin kan tó fẹ́ máa fa ojú rẹ̀ mọ́ra, ó ń ṣe eré ìdárayá tó gbámúṣé

Báwo lo ṣe lè fi hàn pé ò ń fi ìháragàgà “dúró de ìṣípayá àwọn ọmọ Ọlọ́run”?

  • Máa kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì máa gbàdúrà fún ẹ̀mí mímọ́

  • Rí i pé ò ń jàǹfààní látinú àwọn nǹkan tẹ̀mí tí Jèhófà ń fún wa ká bàa lè sún mọ́ ọn

  • Má ṣe jẹ́ kí Sátánì tàn ẹ́ jẹ́ pé àwọn ìlànà Jèhófà ti máa ń ká èèyàn lọ́wọ́ kò jù

  • Máa fi ohun tó ò ń kọ́ sílò

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́