ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 March ojú ìwé 6
  • “Ìwúkàrà Díẹ̀ Ní Í Mú Gbogbo Ìṣùpọ̀ Di Wíwú”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ìwúkàrà Díẹ̀ Ní Í Mú Gbogbo Ìṣùpọ̀ Di Wíwú”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìdí Tí Ìyọlẹ́gbẹ́ Fi Jẹ́ Ìpèsè Onífẹ̀ẹ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2015
  • Ìdí Tí Ìyọlẹ́gbẹ́ Fi Jẹ́ Ìṣètò Onífẹ̀ẹ́
    Jí!—1996
  • O Lè Jẹ́ Olóòótọ́ Tí Èèyàn Ẹ Kan Bá Fi Jèhófà Sílẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • Ìfẹ́ Ló Ń Mú Ká Fara Mọ́ Ìbáwí Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 March ojú ìwé 6
Arábìnrin kan tí wọ́n ti yọ lẹ́gbẹ́ ń kúrò nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba lẹ́yìn ìpàdé; ó ń wo bí àwọn ará ṣe ń bá ara wọn sọ̀rọ̀

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 KỌ́RÍŃTÌ 4-6

“Ìwúkàrà Díẹ̀ Ní Í Mú Gbogbo Ìṣùpọ̀ Di Wíwú”

5:1, 2, 5-11, 13

Kí nìdí tá a fi máa ń sọ pé ìfẹ́ ló mú kí Jèhófà ṣètò ìyọlẹ́gbẹ́ nígbà tó jẹ́ pé ó máa ń dunni gan-an tó bá ṣẹlẹ̀?

Ìyọlẹ́gbẹ́ fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ . . .

  • Jèhófà, a sì ń bọlá fún orúkọ mímọ́ rẹ̀.​—1Pe 1:15, 16

  • àwọn ará ìjọ, a sì fẹ́ dáàbò bò wọ́n kí ìwà burúkú máa bàa gbilẹ̀.​—1Kọ 5:6

  • ẹni tó dẹ́ṣẹ̀ náà, a sì fẹ́ ràn án lọ́wọ́, ká sì pe orí rẹ̀ wálé.​—Heb 12:11

Tí wọ́n bá yọ ẹnì kan lẹ́gbẹ́ nínú ìdílé Kristẹni kan, báwo lo ṣe lè ràn wọ́n lọ́wọ́?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́