ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 TÍMÓTÌ 4-6
Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Ọrọ̀
Báwo ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe fi hàn pé a máa túbọ̀ láyọ̀ tá a bá gbájú mọ́ ìjọsìn Jèhófà dípò ọrọ̀?
Ọ̀pọ̀ ìbùkún ló ń dúró de àwọn tó bá tẹ́wọ́ gba iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún
Kí nìdí tí kò fi ṣeé ṣe láti máa jọ́sìn Jèhófà ká tún máa wá ọrọ̀? (Mt 6:24)