Àwọn arákùnrin tí wọ́n dá sílẹ̀ lágọ̀ọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ ní Jámánì, lọ́dún 1945
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Tá a bá sún mọ́ Ọlọ́run, kí ló máa ṣe fún wa?
Bíbélì: 1Pe 5:6, 7
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ọ̀rọ̀ ẹni kọ̀ọ̀kan wa ṣe jẹ Ọlọ́run lọ́kàn tó?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo ni ọ̀rọ̀ ẹni kọ̀ọ̀kan wa ṣe jẹ Ọlọ́run lọ́kàn tó?
Bíbélì: Mt 10:29-31
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run ò gbàgbé wa?
○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run ò gbàgbé wa?
Bíbélì: Sm 139:1, 2, 4
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo láyé wa ṣe máa rí tí Ọlọ́run bá ń tọ́jú wa?