Àlùfáà àgbà wọnú Ibi Mímọ́ Jù Lọ
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Tá a bá sún mọ́ Ọlọ́run, kí ló máa ṣe fún wa?
Bíbélì: 1Pe 5:6, 7
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ọ̀rọ̀ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ṣe jẹ Ọlọ́run lọ́kàn tó?
○● ÌPADÀBẸ̀WÒ
Ìbéèrè: Báwo ni ọ̀rọ̀ ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ṣe jẹ Ọlọ́run lọ́kàn tó?
Bíbélì: Mt 10:29-31
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run ò gbàgbé wa?