MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Nígbà Àkọ́kọ́a
Ìbéèrè: Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run ń bójú tó wa lẹ́nì kọ̀ọ̀kan?
Bíbélì: Mt 10:29-31
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ láti fara da àwọn ìṣòro tá à ń kojú lónìí?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:
Ìpadàbẹ̀wòb
Ìbéèrè: Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń ràn wá lọ́wọ́ láti fara da àwọn ìṣòro tá à ń kojú lónìí?
Bíbélì: Jer 29:11
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Bíbélì ṣe ń tọ́ wa sọ́nà?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: