MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Nígbà Àkọ́kọ́ fún Oṣù November (Àkànṣe Ìwàásù)
Ìbéèrè: Ṣé ìgbà kan ń bọ̀ tí ò ní sí ogun àti ìwà ipá mọ́?
Bíbélì: Sm 37:10, 11
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn nǹkan wo ni Bíbélì sọ tó jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:
Nígbà Àkọ́kọ́ fún Oṣù Decembera
Ìbéèrè: Irú Ìwé Wo Ni Bíbélì?
Bíbélì: Ro 15:4
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn nǹkan wo ni Bíbélì sọ tó jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:
Ìpadàbẹ̀wòb
Ìbéèrè: Àwọn nǹkan wo ni Bíbélì sọ tó jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa?
Bíbélì: Ifi 21:3, 4
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe lè lóye ohun tó wà nínú Bíbélì?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: