ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 September ojú ìwé 8
  • Kí Lo Máa Ṣe Ní Ọdún Ọ̀gbẹlẹ̀?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Lo Máa Ṣe Ní Ọdún Ọ̀gbẹlẹ̀?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Fọkàn Tán Àwọn Arákùnrin Àtàwọn Arábìnrin Rẹ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
  • Fífọkàntánni Ló Ń Mú Kí Ìgbésí Ayé Èèyàn Láyọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Ẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Bí Òpin Ti Ń Sún Mọ́lé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Fún Ìgbẹ́kẹ̀lé Rẹ Nínú Jèhófà Lókun
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 September ojú ìwé 8
Igi tá a gbìn sí etí omi so èso

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Kí Lo Máa Ṣe Ní Ọdún Ọ̀gbẹlẹ̀?

Ó ṣe pàtàkì kéèyàn nígbàgbọ́ kó tó lè gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà. Bí àpẹẹrẹ, ìgbàgbọ́ tó lágbára máa jẹ́ ká gbà pé Jèhófà máa dáàbò bò wá, á sì bójú tó wa. (Sm 23:​1, 4; 78:22) Bá a ṣe ń sún mọ́ òpin ayé yìí, a mọ̀ pé àwọn àdánwò Sátánì á túbọ̀ máa le sí i. (Ifi 12:12) Kí ló máa ràn wá lọ́wọ́?

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ KÍ LO MÁA ṢE NÍ ỌDÚN Ọ̀GBẸLẸ̀? KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  1. Báwo la ṣe dà bí “igi” tá a mẹ́nu kàn nínú Jeremáyà 17:8?

  2. Kí ni ọ̀kan lára ohun tó lè dà bí “ooru”?

  3. Kí ló lè ṣẹlẹ̀ sí “igi” náà, kí sì nìdí?

  4. Kí ni Sátánì fẹ́ bà jẹ́?

  5. Báwo la ṣe dà bí àwọn tó ti ń wọkọ̀ òfúrufú tipẹ́?

  6. Kí nìdí tó fi yẹ ká máa fọkàn tán ẹrú olóòótọ́ àti olóye, àmọ́ kí ló lè dán wa wò?

  7. Kí nìdí tó fi yẹ ká fọkàn tán àwọn ìlànà Bíbélì láìka ohun táwọn èèyàn lè máa sọ?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́