ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | HÉBÉRÙ 11
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ní Ìgbàgbọ́?
Báwo ni ìgbàgbọ́ tó lágbára ṣe máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láwọn ipò yìí?
Tí ètò Ọlọ́run bá fún ẹ níṣẹ́ kan tó kà ẹ́ láyà.—Heb 11:8-10
Tẹ́nì kan tó sún mọ́ ẹ bá kú.—Heb 11:17-19
Tí ìjọba bá fòfin de ìjọsìn wa.—Heb 11:23-26