Àwọn ará ń ṣàtúnṣe sí pápá ìṣeré kan tí wọ́n fẹ́ lò fún àpéjọ agbègbè nílùú Frankfurt lórílẹ̀-èdè Jámánì
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run kọ́ ló ń fìyà jẹ wá?
Bíbélì: Jem 1:13
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló dé tá a fi ń jìyà?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Kí ló dé tá a fi ń jìyà?
Bíbélì: 1Jo 5:19
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tá a bá ń jìyà?
○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tá a bá ń jìyà?
Bíbélì: Ais 63:9
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Ọlọ́run máa ṣe láti fòpin sí ìyà tó ń jẹ wá?