Arákùnrin kan ń dá ọ̀dọ́kùnrin kan lẹ́kọ̀ọ́
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Ṣé Ọlọ́run ló lẹ̀bi ìyà tó ń jẹ wá?
Bíbélì: Job 34:10
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí lohun tó fà á gan-an tá a fi ń jìyà?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Kí lohun tó fà á gan-an tá a fi ń jìyà?
Bíbélì: 1Jo 5:19
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa ṣàtúnṣe gbogbo nǹkan tí Èṣù ti bà jẹ́?
○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa ṣàtúnṣe gbogbo nǹkan tí Èṣù ti bà jẹ́?
Bíbélì: Mt 6:9, 10
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run?