TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Nígbà Àkọ́kọ́
Ìbéèrè: Ṣé Ọlọ́run tiẹ̀ máa ń gbọ́ àdúrà?
Bíbélì: Sm 65:2
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn nǹkan wo la lè bá Ọlọ́run sọ nínú àdúrà?
Ìpadàbẹ̀wò
Ìbéèrè: Àwọn nǹkan wo la lè bá Ọlọ́run sọ nínú àdúrà?
Bíbélì: 1Jo 5:14
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń dáhùn àdúrà wa?