ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 October ojú ìwé 2
  • Máa Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Ṣèwà Hù

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Ṣèwà Hù
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé Ò Ń Jẹ́ Kí “Ọgbọ́n Tó Wá Láti Òkè” Darí Rẹ?
    Sún Mọ́ Jèhófà
  • “Ta Ni Nínú Yín Tí ó Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n Àti Olóye?”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká Tuntun
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2004
  • “Aláyọ̀ Ni Ènìyàn Tí Ó Ti Wá Ọgbọ́n Rí”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 October ojú ìwé 2
Arábìnrin kan ń ronú lórí ohun tó kà nínú Bíbélì, ó rántí ìgbà kan tí èdèkòyédè wáyé láàárín òun àti arábìnrin mí ì, ó sì lọ́ yanjú ọ̀rọ̀ yẹn

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÉMÍÌSÌ 3-5

Máa Fi Ọgbọ́n Ọlọ́run Ṣèwà Hù

3:17

Ọgbọ́n Ọlọ́run máa ń ṣe wá láǹfààní gan-an. Bí àpẹẹrẹ, ó máa ń jẹ́ ká yanjú aáwọ̀, ká sì wà ní àlàáfíà pẹ̀lú àwọn ará wa. Tá a bá ń fi ọgbọ́n Ọlọ́run ṣèwà hù, ó máa hàn nínú ìwà wa.

BI ARA RẸ PÉ: ‘Èwo nínú àwọn ànímọ́ yìí ni mo fi hàn láìpẹ́ yìí? Báwo ni mo ṣe lè sunwọ̀n sí i nínú bí mo ṣe ń fáwọn ànímọ́ yìí hàn?’

  • Kí n jẹ́ mímọ́

  • Kí n lẹ́mìí àlàáfíà

  • Kí n máa fòye báni lò

  • Kí n ṣe tán láti ṣègbọràn

  • Kí n máa ń ṣàánú gan-an, kí n sì máa so èso rere

  • Kí n má ṣe ojúsàájú

  • Kí n má sì ṣe àgàbàgebè

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́