ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 13-16
Má Ṣe Bẹ̀rù Àwọn Ẹranko Abàmì Náà
Tá a bá mọ ohun táwọn ẹranko inú Ìfihàn orí 13 dúró fún, ìyẹn ò ní jẹ́ ká máa bẹ̀rù wọn tàbí ká máa gbé wọn gẹ̀gẹ̀ bíi táwọn èèyàn ayé.
Tọ́ka sí ohun tí ẹranko kọ̀ọ̀kan dúró fún
ẸRANKO
Dírágónì náà.—Ifi 13:1, àlàyé ìsàlẹ̀
Ẹranko tó ní ìwo mẹ́wàá àti orí méje.—Ifi 13:1, 2
Ẹranko tó ní ìwo méjì bí ọ̀dọ́ àgùntàn.—Ifi 13:11
Ère ẹranko náà.—Ifi 13:15
OHUN TÓ DÚRÓ FÚN
Agbára Ayé Gẹ̀ẹ́sì àti Amẹ́ríkà
Ìmùlẹ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè àti Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè tó rọ́pò rẹ̀
Sátánì Èṣù
Gbogbo ìjọba tó ń ta ko Ọlọ́run