ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 April ojú ìwé 5
  • Ṣé Ò Ń Jìjàkadì Kó O Lè Gba Ìbùkún?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ò Ń Jìjàkadì Kó O Lè Gba Ìbùkún?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Fi Taratara Wá Ìbùkún Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Ìgbà Wo Ni Jèhófà Máa Ń Bù Kún—Ìsapá Tí A Fi Taratara Ṣe?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • Máa Jà Fitafita Kó O Lè Rí Ìbùkún Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2016
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 April ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 32-33

Ṣé Ò Ń Jìjàkadì Kó O Lè Gba Ìbùkún?

32:24-28

Kí Jèhófà lè bù kún wa, a gbọ́dọ̀ sapá láti máa fi ìjọsìn Jèhófà sípò àkọ́kọ́ láyé wa. (1Kọ 9:26, 27) Nígbà táwa náà bá ń ṣe ohun tó ní ín ṣe pẹ̀lú ìjọsìn Jèhófà, ó yẹ ká ní irú ẹ̀mí tí Jékọ́bù ní. A lè fi hàn pé à ń fi taratara wá ìbùkún Jèhófà tá a bá ń . . .

  • Múra ìpàdé sílẹ̀ dáadáa

  • Wàásù Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run déédéé

  • Ṣe gbogbo ohun tá a lè ṣe láti ran àwọn míì lọ́wọ́ nínú ìjọ

Àwọn àwòrán: Ìyá kan tí ọwọ́ ẹ̀ dí gan-⁠an. 1. Ó gbàdúrà kó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ọjọ́ yẹn. 2. Ó ń fún ọmọ ẹ̀ lóúnjẹ kó tó lọ sí òde ẹ̀rí. 3. Ó wà lóde ẹ̀rí pẹ̀lú àwọn ọmọbìnrin rẹ̀ méjèèjì àti arábìnrin kan, inú ẹ̀ sì ń dùn.

Ipò yòówù kó o wà, máa gbàdúrà déédéé sí Jèhófà pé kó ràn ẹ́ lọ́wọ́, kó sì bù kún ìsapá rẹ láti máa ṣe ìfẹ́ rẹ̀.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn nǹkan wo ló yẹ kí n máa ṣe láti túbọ̀ máa fìtara wá ìbùkún Jèhófà?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́