Bẹ́sálẹ́lì àti Òhólíábù ń ṣe ohun èlò tó máa wà ní àgọ́ ìjọsìn
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Ṣé Bíbélì ṣì wúlò lóde òní?
Bíbélì: 2Ti 3:16
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ṣé Bíbélì àti sáyẹ́ǹsì bára mu?
○● ÌPADÀBẸ̀WÒ
Ìbéèrè: Ṣé Bíbélì àti sáyẹ́ǹsì bára mu?
Bíbélì: Job 26:7
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ṣé àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì ṣì wúlò?