Ábúráhámù ń kọ́ Ísákì ọmọ rẹ̀ nípa Jèhófà
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo la ṣe lè mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú?
Bíbélì: Ais 46:10
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì wo là ń rí tó ń ṣẹ lónìí?
○●○ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì wo là ń rí tó ń ṣẹ lónìí?
Bíbélì: 2Ti 3:1-5
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn nǹkan wo ni Ọlọ́run ṣèlérí pé a máa gbádùn lọ́jọ́ iwájú?
○○●ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Àwọn nǹkan wo ni Ọlọ́run ṣèlérí pé a máa gbádùn lọ́jọ́ iwájú?
Bíbélì: Ais 65:21-23
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Jésù máa ṣe ká lè gbádùn àwọn ìbùkún tí Ọlọ́run ṣèlérí?