ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 October ojú ìwé 2
  • Ẹ Sá fún Ìbọ̀rìṣà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ Sá fún Ìbọ̀rìṣà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Eeṣe ti a Fi Nilati Ṣọra fun Ibọriṣa?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • Báwo La Ṣe Lè Mọ Ìjọsìn Tí Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà?
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Ẹ Ṣọra fun Gbogbo Oniruuru Ibọriṣa
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • Jèhófà Bù Kún Ogunlọ́gọ̀ Èèyàn Tí Ẹnikẹ́ni Kò Lè Kà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 October ojú ìwé 2
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń jó yíká ère ọmọ màlúù.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 31-32

Ẹ Sá fún Ìbọ̀rìṣà

32:1, 4-6, 9, 10

Torí pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti pẹ́ ní Íjíbítì, wọn ò rí ìbọ̀rìṣà bí ohun tó burú mọ́. Lónìí, oríṣiríṣi ọ̀nà lèèyàn lè gbà máa bọ̀rìṣà láìmọ̀. Bó tiẹ̀ jẹ́ pé a ò ní dìídì lọ máa bọ òòṣà, a lè di abọ̀rìṣà tá a bá gbà kí ìfẹ́ ọkàn wa máa darí wa, ìyẹn ò sì ní jẹ́ ká sin Jèhófà tọkàntọkàn mọ́.

Àwòrán: Àwọn tó wà nínú ìdílé kan tó ń ṣe nǹkan ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀. 1. Bàbá ń ṣe àfikún iṣẹ́ nídìí iṣẹ́ káfíńtà. 2. Ọmọdékùnrin kan ń ṣeré. 3. Ìyá ń ra oríṣiríṣi nǹkan lọ́jà.

Àwọn nǹkan wo ni mò ń ṣe tó lè mú kó nira fún mi láti máa sin Jèhófà tọkàntọkàn, kí ni mo lè ṣe láti borí wọn?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́